Text
stringlengths
1
10.7k
Text Number
int64
0
31
License
stringclasses
6 values
Text By
stringclasses
463 values
Translation By
stringlengths
1
146
Language
stringclasses
188 values
File Name
stringlengths
9
81
Source
stringclasses
16 values
ISO639-3
stringclasses
178 values
Script
stringclasses
23 values
Parallel ID
stringclasses
822 values
Story Category
stringclasses
4 values
Ó wà lókè lókè ní ọ̀run. Ó wà sórí òṣùpá. Ó ti lọ!
15
CC-BY
Marion Drew
Victor Williamson, Blessing Williamson
yo
0143_bóòlù-mi-tí-ó-púpa.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0143
asp
Ajao, àdán kan, sùn sí ilé rẹ̀ nínú àárẹ̀. Kòsí ẹnikẹ́ni tí ó yojú sí i.
0
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Lẹ́yìn náà, Ajao kú.
1
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn aládùúgbò ní, "Ajao ti kú, a gbọdọ̀ pe àwọn ẹbí rẹ̀ láti wá sín."
2
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn aládùúgbò lọ pe àwọn ẹyẹ pé, "Ìkan lára yín ti kú."
3
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn ẹyẹ wá, wọ́n sì ri pé Ajao ni. Wọ́n ní, "Ẹranko yìí kì í ṣe ara ẹbí wa."
4
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
"Gbogbo ẹbí wa ní ìyẹ́ ṣùgbọ́n Ajao kò ní nǹkankan. Nítorí náà, kì í ṣe ara wa." Àwọn ẹyẹ náà sálọ.
5
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn aládùúgbò ronú papọ̀, wọ́n ní, "Òòtọ́ ni àwọn ẹyẹ sọ. Ajao kò ní ìyẹ́. Nítorí náà, kì í ṣe ara wọn."
6
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Ìkan lára wọn ní, "Ó gbọdọ̀ jẹ́ ìkan lára àwọn eku. Ó jọ wọ́n."
7
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn aládùúgbò lọ pe àwọn eku pé, "Ìkan lára àwọn ẹbí yín ti kú."
8
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Àwọn eku wá, wọ́n sì ri pé Ajao ni. Wọ́n ní, "Ẹranko yìí kì í ṣe ara ẹbí wa."
9
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
"Gbogbo ẹbí wa ní ìrù ṣùgbọ́n Ajao kò ní ìrù."Àwọn eku náà rìn lọ.
10
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
A kò rí ẹbí fún Ajao, ó sì wà bẹ́ẹ̀ láì sí ẹni tí yóò sín in.
11
CC-BY
Taiwo Ẹhinẹni
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0178_ìdí-tí-wọn-kò-sin-ajao.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0178
asp
Òòrùn pinnu láti lọ kí àbúrò rẹ̀ obìnrin, òṣùpá. Òṣùpá ń gbé ní òdìkejì òfuurufú.‘Mo máa padà dé láìpẹ́, Òòrùn sọ fún ìkuukù.
0
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Kò pẹ́ tí Òòrùn jáde lọ, àwọn òkè wé gèlè funfun.
1
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Afẹ́fẹ́ ń ṣàríyànjiyàn pẹ̀lú àwọn igi. Inú bí àwọn igi. Wọ́n fọ́n gbogbo ewé wọn ká ibi gbogbo.
2
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Òfuurufú bẹ̀rẹ̀ sí i kùn.Ó yírá padà sí òféèfé.
3
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Inú àwọn ìkuukù kò dùn láti rí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.Ẹkún púpọ̀ wà.
4
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Gbogbo àgbáyé bẹ̀rẹ̀ sí í rì wọnú omi lọ.
5
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Bẹ́ẹ̀ kẹ̀dẹ̀ ré, ní apá kejì òfuurufú, Òòrùn ti ṣetán láti kúrò lọ́dọ̀ àbúrò rẹ̀. Wọ́n fẹnu konu, ó kí òṣùpá pé ó dìgbà ó sì padà sí ilé.
6
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Inú òfuurufù dùn púpọ̀ láti rí Òòrùn tó bẹ́ẹ̀ tí ó sì yípadà sí àwọ̀ búlù.Àwọn òkè wọ àsọ aláwọ̀-ewé wọn.
7
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Afẹ́fẹ́ lọ sùn. Awọn igi na ẹ̀ka wọn, wọ́n sì rẹ́rìn-ín.
8
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Inú àwọn ìkuukù dùn láti rí Òòrùn padà. Wọ́n jádé lọ ṣeré.
9
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Ọ̀pọ̀ àwọn ewéko kéèkèèké hù jáde láti inú ilẹ̀ láti ṣe “ báwo ni?” Gbogbo àgbáyé ń tàn yinrin.
10
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
Òòrún tan ìtànṣán rẹ̀ sí ibi gbogbo. Pẹ̀lú ayọ̀, ó ní “Mo wí fún yín pé n óò padà wá.”
11
CC-BY
Khothatso Ranoosi, Marion Drew
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0216_ọjọ́-tí-òòrùn-rin-ìrinajò.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0216
asp
O gbẹ.
0
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Òrùn gbóná.
1
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Afẹfẹ jẹ.
2
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Awọsanma ni.
3
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
O tùtù.
4
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Òjò nró.
5
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Àrá wà.
6
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Mo rí òṣùmàrè kan.
7
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Rachel Oladejo
yo
0231_ìwé-òjò.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0231
asp
Padà wá, olóńgbò! Ṣeré pẹ̀lú mi.
0
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Jòkó sínú apẹ̀rẹ̀ rẹ. Dúró síbí!
1
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Padà wá, olóńgbò! Ọ̀nà yẹn ti ga jù.
2
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Padà wá, olóńgbò! Má lọ síta.
3
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
null
4
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
null
asp_0284
asp
Padà wá, olóńgbò! Iyẹn kì í ṣe tìrẹ.
5
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Padà wá, olóńgbò! Kí ni o ní?
6
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Padà wá, olóńgbò! Iyẹn kì í ṣe ọ̀rẹ́ rẹ.
7
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Báwo ni, olóńgbò! Ṣé o ti padà?
8
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Dúró sínú apẹ̀rẹ̀ rẹ. Àkókò oorun ti yá.
9
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
Olóńgbò?
10
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0284
asp
null
11
CC-BY
Nicola Rijsdijk
Taiwo Ẹhinẹni
yo
0284_pada-wa-olongbo.md
global-asp/asp-source
yor
null
asp_0284
asp
Wo íná!
0
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Ínán jo.
1
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Íná dáno.
2
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Íná n fun ígbóná.
3
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Íná n fun ni ímólé.
4
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Wo, íná!
5
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Íná jẹ iyanú.
6
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
O si làgbàrà.
7
CC-BY
Deborah Namugosa, Beatrice Nabune, Alison Tukei, Rose Sabano
Rachel Oladejo
yo
0302_íná.md
global-asp/asp-new
yor
Latn
asp_0302
asp
Gbogbo ènìyàn mọ̀ pé eerin ní imú gígùn.
0
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ṣùgbọ́n ní àyé àtijọ́, imú eerìn kúrú ó sì tóbi.
1
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Lẹ́yìn tí wọ́n bí ọmọ eerin kan. Ó bẹ púpọ̀. Kò sí ẹranko tí kò ní ìbéèrè fún.
2
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ó fẹ́ mọ́ nípa àgùnfọn.Ó bèrè lọ́wọ́ àgùnfọn “Kí ló dé tí o ní ọrùn gígùn?"
3
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Bákan náà ní ó bèrè lọ́wọ́ Túrùkí."Kí lo dé tí ó ni ìhò tí ó ní orí ṣóńṣó?"
4
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ó tún fẹ́ mọ̀ nípa Ọ̀ọ̀nì náà.Ó bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀, “Kí ni àwọn ọ̀ọ̀nì máa ń jẹ fún oúnjẹ alẹ́?”
5
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ẹyẹ Àgbìgbò ọlọ́gbọ́n kan dáa lóhùn,“Tẹ̀lé mi lọ sí odò, níbẹ̀ ni ìwọ yóò ti rí ohun tí ọ̀ọ̀nì ń jẹ fún oúnjẹ alẹ́.”
6
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ọmọ Eerin tẹ̀lé àgbìgbò lọ sí odò.
7
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ó rìn kọjá láàárín àwọn koríkò etí odò láti lè dúró létí odò.Ó wo inú odò.“Níbo ni Ọ̀ọ̀ni wà?”
8
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Òkùta kan tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò náà kí i pé “báwo ni?”Ọmọ Eerin náà dáhùn pé “dáádá ni.” O ní “ ṣe o lè sọ fún mi ohun tí Ọ̀ọ̀nì mán ń jẹ fún oúnjẹ alẹ́?”
9
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Òkùta náà dáhùn pé “ súnmọ́ ibí yìí, n óò sọ ọ́ fún ẹ.” Ọmọ Eerin dorí kodò. Okùta ní “Súnmọ́ ibí dáadáa.”Ọmọ Eerin túbọ̀ dorí kodò.
10
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Lójijì ! À fi pàkà!Ọ̀ọ̀ni di eyín mọ́ imú ọmọ Eerin.
11
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Ọmọ Eerin jókòó, ó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ di ilẹ̀ mú, ó ń fá imú rẹ̀ kúrò lẹ́nu Ọ̀ọ̀nì.Ṣùgbọ́n Ọ̀ọ̀nì kò ju imú rẹ̀ sílẹ̀
12
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Bí ọmọ Eerin ṣe ń fa imú rẹ̀ kúrò lẹnu Ọ̀ọ̀ni, ní imú rẹ̀ ń gùn sí, imú rẹ̀ ń gùn lọ. Kò pẹ́, ọmọ Eerin ṣubú.“kòròbàtà!!”
13
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Imú ọmọ Eerin tí ó kúrú tẹ́lẹ̀ tí gùn jádé.
14
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Imú rẹ̀ gùn gan-an ni, kódà ó lè fi imú rẹ̀ já èèso láti ara ẹ̀ka-igi tí ó ga fíofío. Títí di òní, Eerin ní imú ti ó gùn tí ó sì wúlò fún un.
15
CC-BY
Judith Baker, Lorato Trok
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0312_imú-eerin.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0312
asp
Erin kan fẹ́ lẹ mu omi.
0
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Àgùfọn méjì fẹ́ lọ mu omi.
1
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Ẹfọ̀n mẹ́ta àti ẹyẹ mẹ́rin fẹ́ lọ mu omi.
2
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Ẹtu márùnún àti túrùkú mẹ́fà ń rìn lọ sí ibi omi.
3
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Sẹ́bírà méje ń sáré lọ mu omi.
4
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Kọ̀ǹkọ̀ mẹ́jọ àti ẹja mẹ́sànàn ń wẹ̀ nínú omi.
5
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Kìnìún kan bú ramúramù.Òun náà fẹ́ mu omi Tani ń bẹ̀rù kìnìún?
6
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
Erin kan ń mu omi pẹ̀lú kìnìún.
7
CC-BY
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
yo
0327_kíka-àwọn-ẹranko.md
global-asp/asp-source
yor
Latn
asp_0327
asp
U páanabe’ jach táaj kóom.
0
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
U jool u yotoche’ jach táaj kaabal.
1
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
U ch’aake’ jach táaj kóom.
2
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
U t’íinchak balak’e' jach táaj kaabal.
3
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
¡Le máak je’ela’ jach táaj ka’anal!
4
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Tu meentaj jump’éel chowak ook uti’al u páanab.
5
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Tu nojochkíintaj u joolnajilo’ob u yotoch.
6
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Tu meentaj jump’éel ch’aak jach chowak.
7
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Tu manaj jump’éel ka’anal t’íinchak balak’.
8
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Kulaj ti’ jump’éel jach ka’anal k’áanche’e’ ka j-jaanij yéetel jump’éel jach chowak k’up.
9
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
J-luk’ tu yotoch yo’osal u bin kuxtal ichil jump’éel noj k’áaxil. Te’elo’ kuxlajij ya’abkach ja’abo’ob.
10
CC-BY
Cornelius Gulere
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0001_juntúul-máak-jach-kaanal.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0001
asp
Il a wil le ba’alche’o’obo’.
0
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le xch’upil wakaxo’ ku ya’alik: Muu.
1
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le k’o’ox tamano’ ku ya’alik: Bee, bee.
2
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le tsíimino’ ku ya’alik: Hin.
3
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le k’éek’eno’ ku ya’alik: Oink-oink.
4
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le kaaxo’ ku ya’alik: Cló-cló.
5
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le peek’o’ ku ya’alik: Guau.
6
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le ajkanan ba’alche’o’obo’ ku ya’alik, ¡Chss!
7
CC-BY-NC
Jenny Katz
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0002_il-a-wil-le-baalcheoobo.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0002
asp
Le nook’a’ chowak.
0
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0003_u-nookil-xook.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0003
asp
Le nook’il ke’ela nojoch.
1
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0003_u-nookil-xook.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0003
asp
Le páawa’ nojoch.
2
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0003_u-nookil-xook.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0003
asp
Le k’ax nak’a’…
3
CC-BY-NC
Clare Verbeek, Thembani Dladla, Zanele Buthelezi
Víctor Manuel Canché Yam, Edwin Florencio Koyoc Noh (UIMQroo)
yua
0003_u-nookil-xook.md
global-asp/gasp-mexico
yua
Latn
asp_0003
asp